Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìwé Oníwàásù 5:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ọrọ̀ bá ti ń pọ̀ sí, bẹ́ẹ̀ ni iye àwọn tí yóo máa lò ó yóo máa pọ̀ sí i. Kò sì sí èrè tí ọlọ́rọ̀ yìí ní ju pé ó fi ojú rí ọrọ̀ rẹ̀ lọ.

Ka pipe ipin Ìwé Oníwàásù 5

Wo Ìwé Oníwàásù 5:11 ni o tọ