Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìwé Oníwàásù 4:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọkunrin kan wà tí kò ní ẹnìkan,kò lọ́mọ, kò lárá, bẹ́ẹ̀ ni kò ní ìyekan,sibẹsibẹ làálàá rẹ̀ kò lópin,bẹ́ẹ̀ ni kò ní ìtẹ́lọ́rùn ninu ọrọ̀ rẹ̀.Kò fijọ́ kan bi ara rẹ̀ léèrè rí pé, “Ta ni mò ń ṣe làálàá yìí fúntí mo sì ń fi ìgbádùn du ara mi?”Asán ni èyí pàápàá ati ìmúlẹ̀mófo.

Ka pipe ipin Ìwé Oníwàásù 4

Wo Ìwé Oníwàásù 4:8 ni o tọ