Ṣugbọn ti ẹni tí wọn kò tíì bí rárá,sàn ju ti àwọn mejeeji lọ,nítorí kò tíì rí iṣẹ́ ibití àwọn ọmọ aráyé ń ṣe.