Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìwé Oníwàásù 3:19 BIBELI MIMỌ (BM)

nítorí kò sí ìyàtọ̀ láàrin òpin eniyan ati ti ẹranko. Bí eniyan ṣe ń kú, ni ẹranko ṣe ń kú. Èémí kan náà ni wọ́n ń mí; eniyan kò ní anfaani kankan ju ẹranko lọ; nítorí pé asán ni ohun gbogbo.

Ka pipe ipin Ìwé Oníwàásù 3

Wo Ìwé Oníwàásù 3:19 ni o tọ