Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìwé Oníwàásù 3:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo mọ̀ pé gbogbo ohun tí Ọlọrun ṣe, yóo wà títí lae. Kò sí ohun tí ẹ̀dá lè fi kún un, tabi tí ẹ̀dá lè yọ kúrò níbẹ̀, Ọlọrun ni ó dá a bẹ́ẹ̀ kí eniyan lè máa bẹ̀rù rẹ̀.

Ka pipe ipin Ìwé Oníwàásù 3

Wo Ìwé Oníwàásù 3:14 ni o tọ