Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìwé Oníwàásù 2:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo kó fadaka ati wúrà jọ fún ara mi; mo gba ìṣúra àwọn ọba ati ti àwọn agbègbè ìjọba mi. Mo ní àwọn akọrin lọkunrin ati lobinrin, mo sì ní ọpọlọpọ obinrin tíí mú inú ọkunrin dùn.

Ka pipe ipin Ìwé Oníwàásù 2

Wo Ìwé Oníwàásù 2:8 ni o tọ