Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìwé Oníwàásù 2:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí pé nígbà mìíràn ẹni tí ó ti ṣiṣẹ́ pẹlu ọgbọ́n, ìmọ̀ ati òye yóo fi gbogbo rẹ̀ sílẹ̀ fún ẹni tí kò ṣe làálàá fún wọn. Asán ni èyí pẹlu, nǹkan burúkú sì ni.

Ka pipe ipin Ìwé Oníwàásù 2

Wo Ìwé Oníwàásù 2:21 ni o tọ