Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìwé Oníwàásù 2:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Ta ni ó sì mọ̀ bóyá ọlọ́gbọ́n ni yóo jẹ́, tabi òmùgọ̀ eniyan? Sibẹsibẹ òun ni yóo jọ̀gá lórí gbogbo ohun tí mo fi ọgbọ́n mi kó jọ láyé yìí. Asán ni èyí pẹlu.

Ka pipe ipin Ìwé Oníwàásù 2

Wo Ìwé Oníwàásù 2:19 ni o tọ