Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìwé Oníwàásù 2:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí pé àtọlọ́gbọ́n, àtòmùgọ̀, kò sẹ́ni tíí ranti wọn pẹ́ lọ títí. Nítorí pé ní ọjọ́ iwájú, gbogbo wọn yóo di ẹni ìgbàgbé patapata. Ẹ wo bí ọlọ́gbọ́n ti í kú bí òmùgọ̀.

Ka pipe ipin Ìwé Oníwàásù 2

Wo Ìwé Oníwàásù 2:16 ni o tọ