Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìwé Oníwàásù 2:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, mo bẹ̀rẹ̀ sí ronú nípa ìwà ọlọ́gbọ́n, ìwà wèrè ati ìwà òmùgọ̀. Mo rò ó pé kí ni ẹnìkan lè ṣe lẹ́yìn èyí tí ọba ti ṣe ṣáájú rẹ̀?

Ka pipe ipin Ìwé Oníwàásù 2

Wo Ìwé Oníwàásù 2:12 ni o tọ