Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìwé Oníwàásù 10:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Má bú ọba, kì báà jẹ́ ninu ọkàn rẹ,má sì gbé ọlọ́rọ̀ ṣépè, kì báà jẹ́ ninu yàrá rẹ,nítorí atẹ́gùn lè gbé ọ̀rọ̀ rẹ lọ,tabi kí àwọn ẹyẹ kan lọ ṣòfófó rẹ.

Ka pipe ipin Ìwé Oníwàásù 10

Wo Ìwé Oníwàásù 10:20 ni o tọ