Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìwé Oníwàásù 1:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ohun tí ó ti wà tẹ́lẹ̀ náà ni yóo máa wà. Ohun tí a ti ṣe tẹ́lẹ̀ náà ni a óo tún máa ṣe, kò sí ohun titun kan ní ilé ayé.

Ka pipe ipin Ìwé Oníwàásù 1

Wo Ìwé Oníwàásù 1:9 ni o tọ