Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìwé Oníwàásù 1:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo wí lọ́kàn ara mi pé, “Mo ti kọ́ ọpọlọpọ ọgbọ́n, ju gbogbo àwọn tí wọ́n ti jọba ní Jerusalẹmu ṣáájú mi lọ. Mo ní ọpọlọpọ ìrírí tí ó kún fún ọgbọ́n ati ìmọ̀.”

Ka pipe ipin Ìwé Oníwàásù 1

Wo Ìwé Oníwàásù 1:16 ni o tọ