Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìwé Oníwàásù 1:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo ti wo gbogbo nǹkan tí eniyan ń ṣe láyé, wò ó, asán ati ìmúlẹ̀mófo ni gbogbo rẹ̀.

Ka pipe ipin Ìwé Oníwàásù 1

Wo Ìwé Oníwàásù 1:14 ni o tọ