Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 9:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ògo Ọlọrun Israẹli ti gbéra kúrò lórí àwọn Kerubu tí ó wà, ó dúró sí àbáwọlé. Ó ké sí ọkunrin tí ó wọ aṣọ funfun náà, tí ó sì ní àpótí ìkọ̀wé kan lẹ́gbẹ̀ẹ́.

Ka pipe ipin Isikiẹli 9

Wo Isikiẹli 9:3 ni o tọ