Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 8:6 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA sọ fún mi pé: “Ọmọ eniyan, ṣé o rí ohun tí wọn ń ṣe? Ṣé o rí nǹkan ìríra ńlá tí àwọn ọmọ Israẹli ń ṣe níhìn-ín láti lé mi jìnnà sí ilé mímọ́ mi? N óo fi nǹkan ìríra ńlá mìíràn hàn ọ́.”

Ka pipe ipin Isikiẹli 8

Wo Isikiẹli 8:6 ni o tọ