Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 8:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó na nǹkankan tí ó dàbí ọwọ́, ó fi gbá ìdí irun orí mi mú, ẹ̀mí sì gbé mi sókè sí agbede meji ọ̀run ati ayé, ó gbé mi lọ sí Jerusalẹmu, ninu ìran Ọlọrun, ó gbé mi sí ẹnu ọ̀nà àgbàlá gbọ̀ngàn ti inú tí ó kọjú sí ìhà àríwá, níbi tí wọ́n gbé ère tí ń múni jowú sí.

Ka pipe ipin Isikiẹli 8

Wo Isikiẹli 8:3 ni o tọ