Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 8:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó bi mí pé: “Ọmọ eniyan, ṣé o rí ohun tí wọn ń ṣe yìí? Ṣé nǹkan ìríra tí àwọn ọmọ ilé Juda ń ṣe níhìn-ín kò jọ wọ́n lójú ni wọ́n ṣe mú kí ìwà ìkà kún ilẹ̀ yìí, tí wọn ń mú mi bínú sí i? Wò bí wọ́n ti ń tàbùkù mi, tí wọn ń fín mi níràn.

Ka pipe ipin Isikiẹli 8

Wo Isikiẹli 8:17 ni o tọ