Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 8:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo bá wọlé láti wo ohun tí ó wà níbẹ̀. Mo rí àwòrán oríṣìíríṣìí kòkòrò ati ti ẹranko, tí ń rí ni lára, ati gbogbo oriṣa àwọn ọmọ Israẹli tí wọ́n yà sí ara ògiri yíká.

Ka pipe ipin Isikiẹli 8

Wo Isikiẹli 8:10 ni o tọ