Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 7:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n ń lo ohun ọ̀ṣọ́ wọn dáradára fún ògo asán; òun ni wọ́n fi ń ṣe àwọn ère ati oriṣa wọn, àwọn ohun ìríra tí wọn ń bọ. Nítorí náà, OLUWA óo sọ wọ́n di ohun àìmọ́ fún wọn.

Ka pipe ipin Isikiẹli 7

Wo Isikiẹli 7:20 ni o tọ