Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 7:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Ogun ń bẹ lóde; àjàkálẹ̀-àrùn ati ìyàn wà ninu ilé. Ẹni tí ó bá wà lóko yóo kú ikú ogun. Ìyàn ati àjàkálẹ̀-àrùn yóo pa ẹni tí ó bá wà ninu ìlú.

Ka pipe ipin Isikiẹli 7

Wo Isikiẹli 7:15 ni o tọ