Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 6:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn pẹpẹ ìrúbọ yín yóo di ahoro, a óo fọ́ àwọn pẹpẹ turari yín, n óo sì da òkú yín sílẹ̀ níwájú àwọn oriṣa yín.

Ka pipe ipin Isikiẹli 6

Wo Isikiẹli 6:4 ni o tọ