Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 5:17 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo rán ìyàn ati àwọn ẹranko burúkú si yín, wọn óo sì pa yín lọ́mọ. Àjàkálẹ̀ àrùn ati ikú yóo bẹ́ sílẹ̀ láàrin yín, n óo sì jẹ́ kí ogun pa yín. Èmi OLUWA ni mo sọ bẹ́ẹ̀.”

Ka pipe ipin Isikiẹli 5

Wo Isikiẹli 5:17 ni o tọ