Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 5:1 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA ní: “Ìwọ ọmọ eniyan, mú idà kan tí ó bá mú, lò ó gẹ́gẹ́ bí abẹ ìfárí, kí o fi fá orí ati irùngbọ̀n rẹ. Mú òṣùnwọ̀n tí a fi ń wọn nǹkan kí o fi pín irun tí o bá fá sí ọ̀nà mẹta.

Ka pipe ipin Isikiẹli 5

Wo Isikiẹli 5:1 ni o tọ