Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 48:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọ̀kọ̀ọ̀kan ninu ẹ̀gbẹ́ mẹrẹẹrin ìlú náà yóo gùn ní ẹgbaa meji ó lé ẹẹdẹgbẹta (4,500) igbọnwọ (mita 2,250), ati ti ìlà oòrùn, ati ti ìwọ̀ oòrùn, ati ti àríwá ati ti gúsù.

Ka pipe ipin Isikiẹli 48

Wo Isikiẹli 48:16 ni o tọ