Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 48:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọn kò gbọdọ̀ tà ninu rẹ̀, wọn kò gbọdọ̀ fi yáwó, wọn kò sì gbọdọ̀ fún ẹlòmíràn lára ilẹ̀ tí a yà sọ́tọ̀ yìí; nítorí pé mímọ́ ni, ti OLUWA sì ni.

Ka pipe ipin Isikiẹli 48

Wo Isikiẹli 48:14 ni o tọ