Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 48:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Lọ́tọ̀ ni a óo fún wọn ní ilẹ̀ tiwọn. Yóo jẹ́ ìpín tiwọn lára ilẹ̀ tí a yà sọ́tọ̀ fún OLUWA, ilẹ̀ mímọ́ jùlọ; yóo wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ ilẹ̀ ti àwọn ọmọ Lefi.

Ka pipe ipin Isikiẹli 48

Wo Isikiẹli 48:12 ni o tọ