Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 47:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó tún wọn ẹgbẹrun igbọnwọ (mita 450) mìíràn sí ìsàlẹ̀, ó sì mú mi la odò náà kọjá: odò yìí sì mù mí dé orúnkún. Ọkunrin náà tún wọn ẹgbẹrun igbọnwọ (mita 450) mìíràn sí ìsàlẹ̀, ó tún mú mi la odò náà kọjá: ó sì mù mí dé ìbàdí.

Ka pipe ipin Isikiẹli 47

Wo Isikiẹli 47:4 ni o tọ