Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 47:13 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA Ọlọrun ní, “Èyí ni yóo jẹ́ ààlà tí ẹ óo fi pín ilẹ̀ láàrin àwọn ẹ̀yà Israẹli mejeejila. Josẹfu yóo ní ìpín meji;

Ka pipe ipin Isikiẹli 47

Wo Isikiẹli 47:13 ni o tọ