Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 46:1 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA Ọlọrun ní, “Ẹnu ọ̀nà àgbàlá inú tí ó kọjú sí ìlà oòrùn gbọdọ̀ wà ní títì fún ọjọ́ mẹfa tí a fi ń ṣiṣẹ́. Ṣugbọn ẹ máa ṣí i ní ọjọ́ ìsinmi ati ọjọ́ oṣù tuntun.

Ka pipe ipin Isikiẹli 46

Wo Isikiẹli 46:1 ni o tọ