Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 45:6 BIBELI MIMỌ (BM)

“Lára ilẹ̀ mímọ́ náà, ẹ óo ya apá kan sọ́tọ̀ tí òòró rẹ̀ yóo jẹ́ ọ̀kẹ́ kan ati ẹẹdẹgbaata (25,000) igbọnwọ (kilomita 12½), tí ìbú rẹ̀ yóo sì jẹ́ ẹẹdẹgbaata (5,000) igbọnwọ (kilomita 2½), ilẹ̀ yìí yóo wà fún gbogbo àwọn ọmọ Israẹli.

Ka pipe ipin Isikiẹli 45

Wo Isikiẹli 45:6 ni o tọ