Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 45:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Alufaa yóo mú díẹ̀ ninu ẹ̀jẹ̀ ẹbọ ìmúkúrò ẹ̀ṣẹ̀, yóo fi sí ara òpó ìlẹ̀kùn tẹmpili, ati orígun mẹrẹẹrin pẹpẹ ati òpó ìlẹ̀kùn àbáwọlé gbọ̀ngàn ààrin ilé.

Ka pipe ipin Isikiẹli 45

Wo Isikiẹli 45:19 ni o tọ