Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 45:13 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ohun tí ẹ óo máa fi rúbọ sí OLUWA nìwọ̀nyí: ìdámẹ́fà òṣùnwọ̀n eefa kan ninu òṣùnwọ̀n homeri ọkà yín kọ̀ọ̀kan, ati ìdámẹ́fà òṣùnwọ̀n eefa kan ninu òṣùnwọ̀n homeri alikama yín kọ̀ọ̀kan.

Ka pipe ipin Isikiẹli 45

Wo Isikiẹli 45:13 ni o tọ