Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 44:9 BIBELI MIMỌ (BM)

“ ‘Nítorí náà, ẹni tí kò bá kọlà ọkàn ati ti ara ninu àwọn àlejò tí wọn ń gbé ààrin àwọn ọmọ Israẹli kò gbọdọ̀ wọ ibi mímọ́ mi. Èmi OLUWA ni mo sọ bẹ́ẹ̀.’ ”

Ka pipe ipin Isikiẹli 44

Wo Isikiẹli 44:9 ni o tọ