Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 44:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ẹ̀ ń gbà fún àwọn àlejò, tí a kò kọ nílà abẹ́, ati ti ọkàn, láti máa wọ ibi mímọ́ mi nígbà tí ẹ bá ń fi ọ̀rá ati ẹ̀jẹ̀ rú ẹbọ sí mi, ibi mímọ́ mi ni ẹ̀ ń sọ di aláìmọ́. Ẹ ti fi àwọn ohun ìríra yín ba majẹmu mi jẹ́.

Ka pipe ipin Isikiẹli 44

Wo Isikiẹli 44:7 ni o tọ