Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 44:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà, ọkunrin náà mú mi gba ẹnu ọ̀nà ìhà àríwá wá siwaju tẹmpili; mo sì rí i tí ìtànṣán ògo OLUWA kún inú tẹmpili, mo bá dojúbolẹ̀.

Ka pipe ipin Isikiẹli 44

Wo Isikiẹli 44:4 ni o tọ