Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 44:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo àkọ́so oniruuru èso ati oniruuru ọrẹ gbọdọ̀ jẹ́ ti àwọn alufaa. Ẹ sì gbọdọ̀ fún àwọn alufaa mi ní àkọ́pò ìyẹ̀fun yín kí ibukun lè wà ninu ilé yín.

Ka pipe ipin Isikiẹli 44

Wo Isikiẹli 44:30 ni o tọ