Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 44:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọjọ́ tí ó bá lọ sí ibi mímọ́, tí ó bá lọ sinu gbọ̀ngàn inú láti ṣiṣẹ́ iranṣẹ ní ibi mímọ́, ó gbọdọ̀ rú ẹbọ ìmúkúrò ẹ̀ṣẹ̀. Èmi OLUWA Ọlọrun ni mo sọ bẹ́ẹ̀.

Ka pipe ipin Isikiẹli 44

Wo Isikiẹli 44:27 ni o tọ