Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 44:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí wọ́n bá ti dé àwọn ẹnu ọ̀nà gbọ̀ngàn inú, wọn yóo wọ aṣọ funfun. Wọn kò ní wọ ohunkohun tí a fi irun aguntan hun nígbà tí wọ́n bá ń ṣiṣẹ́ iranṣẹ lẹ́nu ọ̀nà ati ninu gbọ̀ngàn inú.

Ka pipe ipin Isikiẹli 44

Wo Isikiẹli 44:17 ni o tọ