Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 44:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n lè jẹ́ iranṣẹ ninu ibi mímọ́ mi, wọ́n lè máa ṣe alákòóso àwọn ẹnu ọ̀nà tẹmpili, wọ́n lè máa ṣiṣẹ́ ninu tẹmpili, wọ́n lè máa pa ẹran ẹbọ sísun ati ẹran ẹbọ àwọn eniyan, wọ́n lè máa ṣe iranṣẹ fún àwọn eniyan.

Ka pipe ipin Isikiẹli 44

Wo Isikiẹli 44:11 ni o tọ