Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 43:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Fún ọjọ́ meje ni ẹ óo fi máa rú ẹbọ ìwẹ̀nùmọ́ fún pẹpẹ náà tí ẹ óo sì máa yà á sí mímọ́; bẹ́ẹ̀ ni ẹ óo ṣe yà á sọ́tọ̀ fún lílò.

Ka pipe ipin Isikiẹli 43

Wo Isikiẹli 43:26 ni o tọ