Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 43:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Orí pẹpẹ náà ga ní igbọnwọ mẹrin (mita meji). Ìwo mẹrin wà lára rẹ̀, wọ́n gùn ní igbọnwọ kọ̀ọ̀kan (ìdajì mita kan).

Ka pipe ipin Isikiẹli 43

Wo Isikiẹli 43:15 ni o tọ