Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 42:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Nísàlẹ̀ àwọn yàrá wọnyi, ọ̀nà kan wà ní apá ìlà oòrùn bí eniyan bá ti ń bọ̀ láti ibi gbọ̀ngàn ìta.

Ka pipe ipin Isikiẹli 42

Wo Isikiẹli 42:9 ni o tọ