Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 42:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọ̀nà kan wà níwájú àwọn yàrá tí ó lọ sinu, ó fẹ̀ ní igbọnwọ mẹ́wàá (mita 5), ó sì gùn ní ọgọrun-un (100) igbọnwọ (mita 50), àwọn ìlẹ̀kùn rẹ̀ wà ní ìhà àríwá.

Ka pipe ipin Isikiẹli 42

Wo Isikiẹli 42:4 ni o tọ