Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 41:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo rí i pé Tẹmpili náà ní pèpéle tí ó ga yíká. Ìpìlẹ̀ àwọn yàrá ẹ̀gbẹ́ jẹ́ ọ̀pá kan tí ó gùn ní igbọnwọ gígùn mẹfa (mita 3).

Ka pipe ipin Isikiẹli 41

Wo Isikiẹli 41:8 ni o tọ