Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 41:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà, ó wọn ògiri tẹmpili, ó nípọn ní igbọnwọ mẹfa (mita 3), ìbú àwọn yàrá ẹ̀gbẹ́ jẹ́ igbọnwọ mẹrin (bíi mita 2) yípo Tẹmpili náà.

Ka pipe ipin Isikiẹli 41

Wo Isikiẹli 41:5 ni o tọ