Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 40:32 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà, ó mú mi lọ sí ìhà ìlà oòrùn gbọ̀ngàn inú, ó sì wọn ẹnu ọ̀nà rẹ̀, bákan náà ni ó rí pẹlu àwọn yòókù.

Ka pipe ipin Isikiẹli 40

Wo Isikiẹli 40:32 ni o tọ