Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 40:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà, ó mú mi wá sí ibi gbọ̀ngàn inú, lẹ́bàá ẹnu ọ̀nà ìhà gúsù, ó sì wọn ẹnu ọ̀nà náà, bákan náà ni òòró ati ìbú rẹ̀ pẹlu àwọn yòókù.

Ka pipe ipin Isikiẹli 40

Wo Isikiẹli 40:28 ni o tọ