Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 40:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà, ó ṣiwaju mi lọ sí ìhà àríwá; ó wọn ìbú ati òòró ẹnu ọ̀nà kan tí ó wà níbẹ̀ tí ó kọjú sí ìhà àríwá, tí ó sì ṣí sí àgbàlá òde.

Ka pipe ipin Isikiẹli 40

Wo Isikiẹli 40:20 ni o tọ