Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 40:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó mú mi lọ sí ilẹ̀ Israẹli ninu ìran, ó gbé mi sí orí òkè gíga kan. Ó dàbí ẹni pé ìlú kan wà ní ìhà ìsàlẹ̀ òkè náà.

Ka pipe ipin Isikiẹli 40

Wo Isikiẹli 40:2 ni o tọ